Ǹjẹ́ mo kéré?
Ǹjẹ́ mo kéré?

Ìwé aláwòrán Ǹjẹ́ mo kéré? náà ni a ti tumọsi èdè àti ẹ̀ka tí ó lé ní 200 lati ìgbà tí wọ́n ti tẹ jade.

📚  200+ èdè ...

🏛️  WorldCat Libraries

Ìwé Àwọn Ọmọdé Àgbáyé fún Olúkúlùkù Orílẹ̀-èdè lórí Pílánẹ́ẹ̀tì

'Láti Aramaic sí Zulu: Ìwé aláwòrán Ǹjẹ́ mo kéré? náà ni a ti tumọsi èdè àti ẹ̀ka tí ó lé ní 200 lati ìgbà tí wọ́n ti tẹ jade.

Ìtàn náà láti òǹkọ̀wé Philipp Winterberg wà larọwọọto fún gbogbo orílẹ̀-èdè lágbàáyé ó kéré tán ní èdè àjùmọ̀lò kan. O jẹ ìwé ọmọdé àkọ́kọ́ tí àgbáyé tí ó kárí gbogbo obirikiti ilẹ-aye.

Ǹjẹ́ mo kéré? àwọn òǹkàwé àtèwe-àtàgbà bákan náà tẹ̀ lé ọmọbìnrin náà Tamia rin ìrìn àjò tó kún fún àwọn ohun ìyanu. Wọ́n jọ ṣàwárí pé ìwọ̀n ní ààlà àti pé Tamia tọ̀nà gan-an lọ́nà tó wá. “Alárinrin” ni ìdájọ́ ìwé ìròyìn ìṣòwò Eselsohr, “àgbàyanu gidigidi fún àwọn ìdílé elédè méjì, àti àwọn ọmọ ilé ìwé jẹ́lé-ó-sinmi,” ni Börsenblatt sọ àti ìwé ìròyìn alàtúnyẹ̀wò náà Kirkus Reviews fohùn jẹ́jẹ́ ṣe àpọ́nlé “fún àwọn ọmọdé tí wọ́n gbádùn láti máa dúró lórí ojú ìwé tó kún fún àwọn ẹ̀dá onídán àti àwọn àlàyé aibọgbọnmu [...]tí wọ́n sọ ni àwọn ọ̀rọ̀ ṣókí àti àwọn ọ̀rọ̀ tí ń gbà ni lọ́kàn àti àwọn àwòrán ìdánúṣe.” Kà á síwájú síi…

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọpẹ fún gbogbo àwọn onkawe!

"This is baby's favorite book!"Feedback from the United States

"This has been my daughter's favourite book since she was 4 months old. The sentences are nice and short so she doesn't lose interest in the pictures while I'm reading each page."Feedback from the UK

"Muito legal esse livro. Singelo, divertido e relacionado ao universo da criança. Bom pra desenvolver o vocabulário. As ilustrações são lindas. Meu filho adorou."Feedback from Brazil

"You are small or big depending on with what you relate to. A simple cute book which exactly portrays this message."Feedback from India

"Muy buen libro infantil. Dinámico, orgánico, perfecto para aprender en romaji. De fácil lectura y con una protagonista realmente encantadora"Feedback from Mexico

"Beautifully illustrated and cleverly written."Feedback from Australia

"We are in love with this book!"Feedback from the United Kà á síwájú síi…

Egbert Yí Padà Sí Àwọ̀ Pupa

Ìwé aláwòrán Egbert Yí Padà Sí Àwọ̀ Pupa náà ni a ti tumọsi èdè àti ẹ̀ka tí ó lé ní 100 lati ìgbà tí wọ́n ti tẹ jade.

📚  100+ èdè ...

🏛️  WorldCat Libraries

🎁  PDF